-
1 Àwọn Ọba 6:37-7:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Ní ọdún kẹrin, oṣù Sífì,* wọ́n fi ìpìlẹ̀ ilé Jèhófà lélẹ̀;+ 38 ní ọdún kọkànlá, oṣù Búlì* (ìyẹn, oṣù kẹjọ), wọ́n parí gbogbo iṣẹ́ ilé náà bó ṣe wà nínú àwòrán ilé kíkọ́ rẹ̀.+ Torí náà, ọdún méje ni ó fi kọ́ ọ.
7 Ọdún mẹ́tàlá (13) ló gba Sólómọ́nì láti kọ́ ilé* rẹ̀,+ títí ó fi parí ilé náà látòkèdélẹ̀.+
-