-
1 Àwọn Ọba 5:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àwọn ìránṣẹ́ mi yóò kó wọn wá láti Lẹ́bánónì sí òkun, màá dì wọ́n ní àdìpọ̀ igi gẹdú kí ó lè gba orí òkun lọ sí ibi tí o bá ní kí n kó wọn sí. Màá ní kí wọ́n la àwọn igi náà níbẹ̀, kí o lè kó wọn lọ. Oúnjẹ tí mo bá béèrè fún agbo ilé+ mi ni wàá fi san án pa dà fún mi.”
-