Diutarónómì 4:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Tí ẹ bá wá Jèhófà Ọlọ́run yín níbẹ̀, ó dájú pé ẹ máa rí i+ tí ẹ bá fi gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara* yín wá a.+ 2 Kíróníkà 26:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà náà, gbogbo àwọn èèyàn Júdà mú Ùsáyà+ tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16), wọ́n sì fi í jọba ní ipò Amasááyà+ bàbá rẹ̀. 2 Kíróníkà 26:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó ń wá Ọlọ́run ní ìgbà ayé Sekaráyà, ẹni tó kọ́ ọ láti máa bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́. Ní gbogbo àkókò tó ń wá Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́ mú kí ó láásìkí.+
29 “Tí ẹ bá wá Jèhófà Ọlọ́run yín níbẹ̀, ó dájú pé ẹ máa rí i+ tí ẹ bá fi gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara* yín wá a.+
26 Nígbà náà, gbogbo àwọn èèyàn Júdà mú Ùsáyà+ tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16), wọ́n sì fi í jọba ní ipò Amasááyà+ bàbá rẹ̀.
5 Ó ń wá Ọlọ́run ní ìgbà ayé Sekaráyà, ẹni tó kọ́ ọ láti máa bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́. Ní gbogbo àkókò tó ń wá Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́ mú kí ó láásìkí.+