Jeremáyà 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ni Páṣúrì bá lu wòlíì Jeremáyà, ó sì fi í sínú àbà+ tó wà ní Ẹnubodè Òkè ti Bẹ́ńjámínì, tó wà ní ilé Jèhófà. Máàkù 14:65 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Àwọn kan wá bẹ̀rẹ̀ sí í tutọ́ sí i lára,+ wọ́n sì bo ojú rẹ̀, wọ́n gbá a ní ẹ̀ṣẹ́, wọ́n sì ń sọ fún un pé: “Sọ tẹ́lẹ̀!” Wọ́n gbá a lójú, àwọn òṣìṣẹ́ ilé ẹjọ́ sì mú un.+
2 Ni Páṣúrì bá lu wòlíì Jeremáyà, ó sì fi í sínú àbà+ tó wà ní Ẹnubodè Òkè ti Bẹ́ńjámínì, tó wà ní ilé Jèhófà.
65 Àwọn kan wá bẹ̀rẹ̀ sí í tutọ́ sí i lára,+ wọ́n sì bo ojú rẹ̀, wọ́n gbá a ní ẹ̀ṣẹ́, wọ́n sì ń sọ fún un pé: “Sọ tẹ́lẹ̀!” Wọ́n gbá a lójú, àwọn òṣìṣẹ́ ilé ẹjọ́ sì mú un.+