2 Kíróníkà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn náà, Jèhóṣáfátì ọba Júdà pa dà sí ilé* rẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù láìséwu.*+ 2 Kíróníkà 19:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Síbẹ̀, àwọn ohun rere kan wà tí a rí nínú rẹ,+ nítorí o ti mú àwọn òpó òrìṣà* kúrò ní ilẹ̀ yìí, o sì ti múra ọkàn rẹ sílẹ̀* láti wá Ọlọ́run tòótọ́.”+
3 Síbẹ̀, àwọn ohun rere kan wà tí a rí nínú rẹ,+ nítorí o ti mú àwọn òpó òrìṣà* kúrò ní ilẹ̀ yìí, o sì ti múra ọkàn rẹ sílẹ̀* láti wá Ọlọ́run tòótọ́.”+