ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 14:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Bí Jèhófà ṣe gba Ísírẹ́lì là lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì lọ́jọ́ yẹn nìyẹn,+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì rí òkú àwọn ará Íjíbítì ní etíkun.

  • Sáàmù 110:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Jèhófà yóò wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ;+

      Yóò fọ́ àwọn ọba túútúú ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀.+

       6 Yóò mú ìdájọ́ ṣẹ lórí* àwọn orílẹ̀-èdè;+

      Yóò fi òkú kún ilẹ̀ náà.+

      Yóò fọ́ aṣáájú* ilẹ̀ fífẹ̀* túútúú.

  • Àìsáyà 37:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Áńgẹ́lì Jèhófà wá jáde lọ, ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án ó lé ẹgbẹ̀rún márùn-ún (185,000) ọkùnrin nínú ibùdó àwọn ará Ásíríà. Nígbà tí àwọn èèyàn jí láàárọ̀ kùtù, wọ́n rí òkú nílẹ̀ bẹẹrẹbẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́