2 Kíróníkà 17:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà wà pẹ̀lú Jèhóṣáfátì nítorí pé ó rìn ní àwọn ọ̀nà tí Dáfídì+ baba ńlá rẹ̀ rìn nígbà àtijọ́, kò sì wá àwọn Báálì. 4 Ó wá Ọlọ́run bàbá rẹ̀,+ ó ń pa àṣẹ rẹ̀ mọ́,* kò sì hu ìwà tí Ísírẹ́lì ń hù.+
3 Jèhófà wà pẹ̀lú Jèhóṣáfátì nítorí pé ó rìn ní àwọn ọ̀nà tí Dáfídì+ baba ńlá rẹ̀ rìn nígbà àtijọ́, kò sì wá àwọn Báálì. 4 Ó wá Ọlọ́run bàbá rẹ̀,+ ó ń pa àṣẹ rẹ̀ mọ́,* kò sì hu ìwà tí Ísírẹ́lì ń hù.+