-
2 Àwọn Ọba 11:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Lẹ́yìn náà, Jèhóádà dá májẹ̀mú láàárín Jèhófà àti ọba àti àwọn èèyàn náà,+ pé àwọn á máa jẹ́ èèyàn Jèhófà nìṣó, ó sì tún dá májẹ̀mú láàárín ọba àti àwọn èèyàn náà.+ 18 Lẹ́yìn ìyẹn, gbogbo àwọn èèyàn ilẹ̀ náà wá sí ilé* Báálì, wọ́n wó àwọn pẹpẹ rẹ̀ lulẹ̀,+ wọ́n fọ́ àwọn ère rẹ̀ túútúú,+ wọ́n sì pa Mátánì àlùfáà Báálì+ níwájú àwọn pẹpẹ náà.
Àlùfáà wá yan àwọn alábòójútó lórí ilé Jèhófà.+
-