ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 20:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 O ò gbọ́dọ̀ ní ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.*+

  • Ẹ́kísódù 20:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 O ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún wọn tàbí kí o jẹ́ kí wọ́n tàn ọ́ láti sìn wọ́n,+ torí èmi Jèhófà Ọlọ́run rẹ jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí o máa sin òun nìkan ṣoṣo,+ tó ń fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá jẹ àwọn ọmọ, dórí ìran kẹta àti ìran kẹrin àwọn tó kórìíra mi,

  • Diutarónómì 7:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Kí ẹ dáná sun ère àwọn ọlọ́run wọn tí wọ́n gbẹ́.+ Má ṣe jẹ́ kí ojú rẹ wọ fàdákà àti wúrà tó wà lára wọn, o ò sì gbọ́dọ̀ mú un fún ara rẹ,+ kó má bàa jẹ́ ìdẹkùn fún ọ, torí ohun ìríra ló jẹ́ lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.+

  • 2 Kíróníkà 28:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Nígbà tí Ọba Áhásì wà nínú ìdààmú, ńṣe ló túbọ̀ ń hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà. 23 Ó bẹ̀rẹ̀ sí í rúbọ sí àwọn ọlọ́run àwọn ará Damásíkù  + tí wọ́n ṣẹ́gun rẹ̀,+ ó ń sọ pé: “Nítorí pé àwọn ọlọ́run àwọn ọba Síríà ń ràn wọ́n lọ́wọ́, èmi náà á rúbọ sí wọn kí wọ́n lè ràn mí lọ́wọ́.”+ Àmọ́ ńṣe ni wọ́n ṣàkóbá fún òun àti gbogbo Ísírẹ́lì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́