Nọ́ńbà 4:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ẹ ka àwọn ọmọ Kóhátì+ lára àwọn ọmọ Léfì, ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn, 3 gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ọgbọ̀n (30)+ ọdún sí àádọ́ta (50) ọdún,+ tí wọ́n wà lára àwọn tí a yàn pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé.+ 1 Kíróníkà 23:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọ Kóhátì ni Ámúrámù, Ísárì,+ Hébúrónì àti Úsíélì,+ wọ́n jẹ́ mẹ́rin.
2 “Ẹ ka àwọn ọmọ Kóhátì+ lára àwọn ọmọ Léfì, ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn, 3 gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ọgbọ̀n (30)+ ọdún sí àádọ́ta (50) ọdún,+ tí wọ́n wà lára àwọn tí a yàn pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé.+