2 Kíróníkà 29:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní àkókò yìí, ó ní kí àwọn ọmọ Léfì dúró sí ilé Jèhófà, pẹ̀lú síńbálì* àti àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù,+ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Dáfídì + àti ti Gádì+ aríran ọba àti ti wòlíì Nátánì,+ nítorí pé Jèhófà ló pa àṣẹ náà nípasẹ̀ àwọn wòlíì rẹ̀.
25 Ní àkókò yìí, ó ní kí àwọn ọmọ Léfì dúró sí ilé Jèhófà, pẹ̀lú síńbálì* àti àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù,+ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Dáfídì + àti ti Gádì+ aríran ọba àti ti wòlíì Nátánì,+ nítorí pé Jèhófà ló pa àṣẹ náà nípasẹ̀ àwọn wòlíì rẹ̀.