-
Nọ́ńbà 8:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 “Èyí kan àwọn ọmọ Léfì: Kí ẹni tó bá ti pé ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ dara pọ̀ mọ́ àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé.
-
-
1 Kíróníkà 23:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àwọn yìí ni àwọn ọmọ Léfì, bí wọ́n ṣe wà nínú agbo ilé bàbá wọn, àwọn olórí agbo ilé bàbá wọn, àwọn tí wọ́n kà, tí orúkọ wọn sì wà lákọsílẹ̀, tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ìsìn ní ilé Jèhófà, láti ẹni ogún (20) ọdún sókè.
-