-
1 Àwọn Ọba 7:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àwọn ọpọ́n náà wà lórí òpó méjì náà, àwọ̀n sì wà lára ibi tó rí rogodo lápá ìsàlẹ̀ ọpọ́n náà; igba (200) pómégíránétì sì wà lórí àwọn ìlà tó yí ọpọ́n kọ̀ọ̀kan ká.+
-