-
2 Kíróníkà 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ó ṣe àwọn ẹ̀wọ̀n tó dà bí ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn, ó sì fi wọ́n sórí àwọn òpó náà, ó ṣe ọgọ́rùn-ún (100) pómégíránétì, ó sì fi wọ́n sára àwọn ẹ̀wọ̀n náà.
-
-
Jeremáyà 52:22, 23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Bàbà ni wọ́n fi ṣe ọpọ́n tó wà lórí rẹ̀; gíga ọpọ́n kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún;+ bàbà ni wọ́n fi ṣe àwọ̀n àti àwọn pómégíránétì tó yí ọpọ́n náà ká. Òpó kejì dà bíi ti àkọ́kọ́ gẹ́lẹ́, bákan náà sì ni àwọn pómégíránétì rẹ̀. 23 Àwọn pómégíránétì mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún (96) ló wà lẹ́gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ rẹ̀; lápapọ̀, gbogbo pómégíránétì tó yí àwọ̀n náà ká jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100).+
-