Ẹ́sírà 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí ọba mọ̀ pé tí wọ́n bá tún ìlú náà kọ́, tí wọ́n sì parí àwọn ògiri rẹ̀, wọn ò ní san owó orí tàbí ìṣákọ́lẹ̀,*+ bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní san owó ibodè, èyí sì máa jẹ́ kí owó tó ń wọlé sí àpò ọba* dín kù.
13 Kí ọba mọ̀ pé tí wọ́n bá tún ìlú náà kọ́, tí wọ́n sì parí àwọn ògiri rẹ̀, wọn ò ní san owó orí tàbí ìṣákọ́lẹ̀,*+ bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní san owó ibodè, èyí sì máa jẹ́ kí owó tó ń wọlé sí àpò ọba* dín kù.