-
2 Àwọn Ọba 23:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Jèhóákímù fún Fáráò ní fàdákà àti wúrà náà, àmọ́ ṣe ló bu owó orí lé ilẹ̀ náà, kó lè fún Fáráò ní fàdákà tó béèrè. Ó gba iye fàdákà àti wúrà tí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn èèyàn ilẹ̀ náà máa san, kó lè fún Fáráò Nẹ́kò.
-