ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ẹ́sírà yìí dé láti Bábílónì. Ó jẹ́ adàwékọ* tó mọ Òfin Mósè+ dunjú,* èyí tó wá látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Gbogbo ohun tó béèrè ni ọba fún un, nítorí ọwọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ wà lára rẹ̀.

  • Ẹ́sírà 7:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Ó ti fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi níwájú ọba+ àti àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ̀+ àti níwájú gbogbo àwọn ìjòyè ọba tí wọ́n jẹ́ alágbára. Torí náà, mo mọ́kàn le* nítorí ọwọ́ Jèhófà Ọlọ́run mi wà lára mi, mo sì kó àwọn aṣáájú ọkùnrin* jọ látinú Ísírẹ́lì kí wọ́n lè bá mi lọ.

  • Ẹ́sírà 8:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ó tì mí lójú láti ní kí ọba fún wa ní àwọn ọmọ ogun àti àwọn agẹṣin láti dáàbò bò wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá lójú ọ̀nà, torí a ti sọ fún ọba pé: “Ọwọ́ rere Ọlọ́run wa wà lára gbogbo àwọn tó ń wá a,+ àmọ́ agbára rẹ̀ àti ìbínú rẹ̀ wà lórí gbogbo àwọn tó fi í sílẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́