ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 5:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nígbà náà, wòlíì Hágáì+ àti wòlíì Sekaráyà+ ọmọ ọmọ Ídò+ sọ tẹ́lẹ̀ fún àwọn Júù tó wà ní Júdà àti ní Jerúsálẹ́mù, ní orúkọ Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń darí wọn. 2 Ìgbà náà ni Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì àti Jéṣúà+ ọmọ Jèhósádákì bẹ̀rẹ̀ sí í tún ilé Ọlọ́run kọ́,+ èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù; àwọn wòlíì Ọlọ́run wà pẹ̀lú wọn, wọ́n sì ń tì wọ́n lẹ́yìn.+

  • Sekaráyà 1:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Ní oṣù kẹjọ, ọdún kejì ìjọba Dáríúsì,+ Jèhófà sọ fún wòlíì Sekaráyà*+ ọmọ Berekáyà ọmọ Ídò pé:

  • Sekaráyà 1:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kọkànlá, ìyẹn oṣù Ṣébátì,* ní ọdún kejì ìjọba Dáríúsì,+ Jèhófà bá wòlíì Sekaráyà ọmọ Berekáyà ọmọ Ídò sọ̀rọ̀. Sekaráyà sọ pé:

  • Sekaráyà 6:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwọn tó wà lọ́nà jíjìn yóò wá, wọ́n sì máa wà lára àwọn tí yóò kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.” Ẹ ó sì mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló rán mi sí yín. Yóò sì rí bẹ́ẹ̀, tí ẹ bá fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run yín.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́