ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 1:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nígbà náà, àwọn olórí agbo ilé Júdà àti ti Bẹ́ńjámínì àti àwọn àlùfáà pẹ̀lú àwọn ọmọ Léfì, ìyẹn gbogbo ẹni tí Ọlọ́run tòótọ́ ta ẹ̀mí rẹ̀ jí, múra láti lọ tún ilé Jèhófà kọ́, èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù. 6 Gbogbo àwọn tó wà láyìíká wọn tì wọ́n lẹ́yìn,* wọ́n fún wọn ní àwọn nǹkan èlò fàdákà àti ti wúrà, àwọn ẹrù àti àwọn ẹran ọ̀sìn pẹ̀lú àwọn nǹkan tó ṣeyebíye, yàtọ̀ sí gbogbo ọrẹ àtinúwá.

  • Ẹ́sírà 8:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Lẹ́yìn náà, mo wọn fàdákà àti wúrà pẹ̀lú àwọn nǹkan èlò fún wọn, ọrẹ tí ọba àti àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ àti àwọn ìjòyè rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà níbẹ̀ mú wá fún ilé Ọlọ́run wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́