ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 7:14-16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nítorí ọba àti àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ méje ló rán ọ láti wádìí bóyá wọ́n ń pa Òfin Ọlọ́run rẹ, tó wà pẹ̀lú* rẹ mọ́ ní Júdà àti Jerúsálẹ́mù, 15 kí o sì kó fàdákà àti wúrà tí ọba àti àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ fi ṣe ọrẹ àtinúwá fún Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń gbé ní Jerúsálẹ́mù 16 pẹ̀lú gbogbo fàdákà àti wúrà tí o bá gbà* ní gbogbo ìpínlẹ̀* Bábílónì àti ẹ̀bùn tí àwọn èèyàn náà àti àwọn àlùfáà fi ṣe ọrẹ àtinúwá fún ilé Ọlọ́run wọn, èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù.+

  • Ẹ́sírà 7:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Gbogbo ohun èlò tí wọ́n kó fún ọ fún iṣẹ́ ìsìn ilé Ọlọ́run rẹ ni kí o fi jíṣẹ́ níwájú Ọlọ́run ní Jerúsálẹ́mù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́