Ẹ́sírà 6:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wọ́n tún fi ọjọ́ méje ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ tìdùnnú-tìdùnnú; nítorí Jèhófà ti mú kí wọ́n máa yọ̀, ó sì ti mú kí ọba Ásíríà ṣe ojú rere sí wọn,*+ tí ó fi tì wọ́n lẹ́yìn* lẹ́nu iṣẹ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́, Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Òwe 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọkàn ọba dà bí odò ní ọwọ́ Jèhófà.+ Ibi tí Ó bá fẹ́ ló ń darí rẹ̀ sí.+ Àìsáyà 60:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+
22 Wọ́n tún fi ọjọ́ méje ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ tìdùnnú-tìdùnnú; nítorí Jèhófà ti mú kí wọ́n máa yọ̀, ó sì ti mú kí ọba Ásíríà ṣe ojú rere sí wọn,*+ tí ó fi tì wọ́n lẹ́yìn* lẹ́nu iṣẹ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́, Ọlọ́run Ísírẹ́lì.
13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+