Àìsáyà 41:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Màá gbin igi kédárì sínú aṣálẹ̀,Màá gbin igi bọn-ọ̀n-ní, igi mátílì àti igi ahóyaya síbẹ̀.+ Màá gbin igi júnípà sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú,Pẹ̀lú igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì,+ Àìsáyà 55:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dípò àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún, igi júnípà máa hù,+Dípò èsìsì tó ń jóni lára, igi mátílì máa hù. Ó sì máa mú kí Jèhófà lókìkí,*+Àmì tó máa wà títí láé, tí kò ní pa run.”
19 Màá gbin igi kédárì sínú aṣálẹ̀,Màá gbin igi bọn-ọ̀n-ní, igi mátílì àti igi ahóyaya síbẹ̀.+ Màá gbin igi júnípà sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú,Pẹ̀lú igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì,+ Àìsáyà 55:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dípò àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún, igi júnípà máa hù,+Dípò èsìsì tó ń jóni lára, igi mátílì máa hù. Ó sì máa mú kí Jèhófà lókìkí,*+Àmì tó máa wà títí láé, tí kò ní pa run.”
13 Dípò àwọn igi ẹlẹ́gùn-ún, igi júnípà máa hù,+Dípò èsìsì tó ń jóni lára, igi mátílì máa hù. Ó sì máa mú kí Jèhófà lókìkí,*+Àmì tó máa wà títí láé, tí kò ní pa run.”