Ẹ́sírà 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Níkẹyìn, a ṣí kúrò níbi odò Áháfà+ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kìíní+ láti lọ sí Jerúsálẹ́mù, ọwọ́ Ọlọ́run wa sì wà lára wa, ó gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá lójú ọ̀nà àti lọ́wọ́ àwọn dánàdánà.
31 Níkẹyìn, a ṣí kúrò níbi odò Áháfà+ ní ọjọ́ kejìlá oṣù kìíní+ láti lọ sí Jerúsálẹ́mù, ọwọ́ Ọlọ́run wa sì wà lára wa, ó gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá lójú ọ̀nà àti lọ́wọ́ àwọn dánàdánà.