-
Ẹ́sírà 8:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Mo kó wọn jọ níbi odò tó ṣàn wá sí Áháfà,+ a sì pàgọ́ síbẹ̀ fún ọjọ́ mẹ́ta. Àmọ́ nígbà tí mo yẹ àwọn èèyàn náà àti àwọn àlùfáà wò, mi ò rí ìkankan lára àwọn ọmọ Léfì níbẹ̀.
-
-
Ẹ́sírà 8:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lẹ́yìn náà, mo kéde ààwẹ̀ níbi odò Áháfà, láti rẹ ara wa sílẹ̀ níwájú Ọlọ́run wa àti láti wá ìtọ́sọ́nà lọ́dọ̀ rẹ̀ fún ìrìn àjò wa, fún àwa àti àwọn ọmọ wa àti fún gbogbo ẹrù wa.
-