-
Ẹ́sírà 8:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nítorí pé ọwọ́ rere Ọlọ́run wa wà lára wa, wọ́n mú ọlọ́gbọ́n ọkùnrin kan wá látinú àwọn ọmọ Máhílì+ ọmọ ọmọ Léfì ọmọ Ísírẹ́lì, orúkọ rẹ̀ ni Ṣerebáyà+ àti àwọn ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀, gbogbo wọn jẹ́ méjìdínlógún (18); 19 wọ́n tún mú Haṣabáyà, Jeṣáyà látinú àwọn ọmọ Mérárì+ sì wà pẹ̀lú rẹ̀, àwọn arákùnrin rẹ̀ àti àwọn ọmọ wọn, gbogbo wọn jẹ́ ogún (20) ọkùnrin.
-