-
Ẹ́sírà 8:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Mo wá ya àwọn méjìlá (12) sọ́tọ̀ lára àwọn olórí àlùfáà, àwọn ni, Ṣerebáyà àti Haṣabáyà+ pẹ̀lú mẹ́wàá lára àwọn arákùnrin wọn. 25 Lẹ́yìn náà, mo wọn fàdákà àti wúrà pẹ̀lú àwọn nǹkan èlò fún wọn, ọrẹ tí ọba àti àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ àti àwọn ìjòyè rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà níbẹ̀ mú wá fún ilé Ọlọ́run wa.+
-