Ẹ́sírà 10:43, 44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 látinú àwọn ọmọ Nébò, Jéélì, Matitáyà, Sábádì, Sébínà, Jádáì, Jóẹ́lì àti Bẹnáyà. 44 Gbogbo àwọn yìí ni wọ́n fẹ́ àwọn aya àjèjì,+ wọ́n sì lé àwọn aya wọn lọ pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn.+
43 látinú àwọn ọmọ Nébò, Jéélì, Matitáyà, Sábádì, Sébínà, Jádáì, Jóẹ́lì àti Bẹnáyà. 44 Gbogbo àwọn yìí ni wọ́n fẹ́ àwọn aya àjèjì,+ wọ́n sì lé àwọn aya wọn lọ pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn.+