-
Nehemáyà 7:39-42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Àwọn àlùfáà nìyí:+ àwọn ọmọ Jedáyà láti ilé Jéṣúà jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́sàn-án ó lé mẹ́tàléláàádọ́rin (973); 40 àwọn ọmọ Ímérì jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé méjìléláàádọ́ta (1,052); 41 àwọn ọmọ Páṣúrì+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé igba àti mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247); 42 àwọn ọmọ Hárímù+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).
-