-
Ẹ́sírà 2:36-39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Àwọn àlùfáà nìyí:+ àwọn ọmọ Jedáyà+ láti ilé Jéṣúà+ jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́sàn-án ó lé mẹ́tàléláàádọ́rin (973); 37 àwọn ọmọ Ímérì+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé méjìléláàádọ́ta (1,052); 38 àwọn ọmọ Páṣúrì+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé igba àti mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247); 39 àwọn ọmọ Hárímù+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).
-