-
Ẹ́sírà 2:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 àwọn ọmọ Élámù+ jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó lé igba àti mẹ́rìnléláàádọ́ta (1,254);
-
-
Ẹ́sírà 8:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn olórí agbo ilé àti àkọsílẹ̀ orúkọ ìdílé àwọn tó tẹ̀ lé mi jáde kúrò ní Bábílónì nígbà ìjọba Ọba Atasásítà nìyí:+
-
-
Ẹ́sírà 8:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 látinú àwọn ọmọ Élámù,+ Jeṣáyà ọmọ Ataláyà, àádọ́rin (70) ọkùnrin sì wà pẹ̀lú rẹ̀;
-