7 Ọba Kírúsì tún kó àwọn nǹkan èlò inú ilé Jèhófà jáde, àwọn tí Nebukadinésárì kó láti Jerúsálẹ́mù, tó sì kó sínú ilé ọlọ́run rẹ̀.+ 8 Kírúsì ọba Páṣíà kó wọn jáde lábẹ́ àbójútó Mítírédátì, ẹni tó ń tọ́jú ìṣúra, ó sì ka iye wọn fún Ṣẹṣibásà+ ìjòyè Júdà.