-
Ẹ́sírà 4:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ìgbà náà ni iṣẹ́ ilé Ọlọ́run, èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù, dáwọ́ dúró; ó sì wà bẹ́ẹ̀ títí di ọdún kejì ìjọba Dáríúsì ọba Páṣíà.+
-
-
Ẹ́sírà 6:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ìgbà náà ni Ọba Dáríúsì pa àṣẹ kan, wọ́n sì ṣe àyẹ̀wò nínú ibi ìkówèésí* tó wà ní àwọn ibi tí wọ́n ń kó ìṣúra sí ní Bábílónì.
-