Nehemáyà 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.
26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.