ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 9:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àwọn tó ń gbé Gíbíónì+ náà gbọ́ ohun tí Jóṣúà ṣe sí Jẹ́ríkò+ àti Áì.+

  • Jóṣúà 9:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Àmọ́ ọjọ́ yẹn ni Jóṣúà sọ wọ́n di aṣẹ́gi àti àwọn tí á máa pọnmi fún àpéjọ náà+ àti pẹpẹ Jèhófà ní ibi tí Ó bá yàn,+ iṣẹ́ tí wọ́n sì ń ṣe títí di òní nìyẹn.+

  • 1 Kíróníkà 9:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àwọn tó kọ́kọ́ pa dà sídìí ohun ìní wọn, ní àwọn ìlú wọn, ni àwọn kan lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì.*+

  • Ẹ́sírà 2:43-54
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* nìyí:+ àwọn ọmọ Síhà, àwọn ọmọ Hásúfà, àwọn ọmọ Tábáótì, 44 àwọn ọmọ Kérósì, àwọn ọmọ Síáhà, àwọn ọmọ Pádónì, 45 àwọn ọmọ Lébánà, àwọn ọmọ Hágábà, àwọn ọmọ Ákúbù, 46 àwọn ọmọ Hágábù, àwọn ọmọ Sálímáì, àwọn ọmọ Hánánì, 47 àwọn ọmọ Gídélì, àwọn ọmọ Gáhárì, àwọn ọmọ Reáyà, 48 àwọn ọmọ Résínì, àwọn ọmọ Nékódà, àwọn ọmọ Gásámù, 49 àwọn ọmọ Úúsà, àwọn ọmọ Páséà, àwọn ọmọ Bésáì, 50 àwọn ọmọ Ásínà, àwọn ọmọ Méúnímù, àwọn ọmọ Néfúsímù, 51 àwọn ọmọ Bákíbúkì, àwọn ọmọ Hákúfà, àwọn ọmọ Háhúrì, 52 àwọn ọmọ Básílútù, àwọn ọmọ Méhídà, àwọn ọmọ Háṣà, 53 àwọn ọmọ Bákósì, àwọn ọmọ Sísérà, àwọn ọmọ Téémà, 54 àwọn ọmọ Nesáyà àti àwọn ọmọ Hátífà.

  • Ẹ́sírà 8:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Mo wá pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n lọ bá Ídò tó jẹ́ olórí ní ibi tí wọ́n ń pè ní Kásífíà. Mo ní kí wọ́n sọ fún Ídò àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* tí wọ́n wà ní Kásífíà pé kí wọ́n bá wa mú àwọn òjíṣẹ́ wá fún ilé Ọlọ́run wa.

  • Ẹ́sírà 8:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Igba ó lé ogún (220) lára àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* wà, tí orúkọ gbogbo wọn wà lákọsílẹ̀. Dáfídì àti àwọn ìjòyè ló ní kí àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì máa ran àwọn ọmọ Léfì lọ́wọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́