ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 22:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 “Tí ẹ bá yá ìkankan nínú àwọn èèyàn mi tó jẹ́ aláìní* lówó, ẹni tó ń bá yín gbé, ẹ ò gbọ́dọ̀ hùwà sí i bí àwọn tó ń yáni lówó èlé.* Ẹ ò gbọ́dọ̀ gba èlé lọ́wọ́ rẹ̀.+

  • Diutarónómì 23:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “O ò gbọ́dọ̀ gba èlé lọ́wọ́ arákùnrin rẹ,+ ì báà jẹ́ èlé lórí owó, lórí oúnjẹ tàbí ohunkóhun tí wọ́n ń gba èlé lé lórí.

  • Sáàmù 15:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Kì í yáni lówó èlé,+

      Kì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti gbógun ti aláìṣẹ̀.+

      Ẹni tó bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí, mìmì kan ò ní mì í láé.*+

  • Ìsíkíẹ́lì 22:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Inú rẹ ni wọ́n ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n lè ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.+ Ò ń yáni lówó èlé,+ ò ń jẹ èrè* lórí owó tí o yáni, o sì ń fipá gba owó lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ.+ Àní, o ti gbàgbé mi pátápátá,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́