Sáàmù 16:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá yin Jèhófà, ẹni tó fún mi ní ìmọ̀ràn.+ Kódà láàárín òru, èrò inú mi* ń tọ́ mi sọ́nà.+ 8 Mo gbé Jèhófà síwájú mi nígbà gbogbo.+ Torí pé ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún mi, mìmì kan ò ní mì mí.*+ Òwe 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìwà burúkú kì í jẹ́ kéèyàn fìdí múlẹ̀,+Àmọ́ kò sí ohun tó lè fa olódodo tu. 2 Pétérù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí náà, ẹ̀yin ará, ẹ túbọ̀ ṣe gbogbo ohun tí ẹ lè ṣe, kí pípè+ àti yíyàn yín lè dá yín lójú, torí tí ẹ bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí, ẹ ò ní kùnà láé.+
7 Màá yin Jèhófà, ẹni tó fún mi ní ìmọ̀ràn.+ Kódà láàárín òru, èrò inú mi* ń tọ́ mi sọ́nà.+ 8 Mo gbé Jèhófà síwájú mi nígbà gbogbo.+ Torí pé ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún mi, mìmì kan ò ní mì mí.*+
10 Torí náà, ẹ̀yin ará, ẹ túbọ̀ ṣe gbogbo ohun tí ẹ lè ṣe, kí pípè+ àti yíyàn yín lè dá yín lójú, torí tí ẹ bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí, ẹ ò ní kùnà láé.+