Nehemáyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí Sáńbálátì+ ará Hórónì àti Tòbáyà + ọmọ Ámónì+ tó jẹ́ òṣìṣẹ́* ọba, gbọ́ nípa rẹ̀, inú wọn ò dùn rárá pé ẹnì kan wá láti wá ṣe ohun rere fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì. Nehemáyà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lásìkò náà, Tòbáyà+ ọmọ Ámónì+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ sọ pé: “Kódà tí kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ bá gun ohun tí wọ́n ń kọ́, ó máa wó ògiri olókùúta wọn lulẹ̀.”
10 Nígbà tí Sáńbálátì+ ará Hórónì àti Tòbáyà + ọmọ Ámónì+ tó jẹ́ òṣìṣẹ́* ọba, gbọ́ nípa rẹ̀, inú wọn ò dùn rárá pé ẹnì kan wá láti wá ṣe ohun rere fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì.
3 Lásìkò náà, Tòbáyà+ ọmọ Ámónì+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ sọ pé: “Kódà tí kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ bá gun ohun tí wọ́n ń kọ́, ó máa wó ògiri olókùúta wọn lulẹ̀.”