Nehemáyà 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tí Sáńbálátì+ gbọ́ pé a ti ń tún ògiri náà mọ, ó bínú, ó fara ya,* ó sì ń fi àwọn Júù ṣe yẹ̀yẹ́. Nehemáyà 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni Sáńbálátì àti Géṣémù ránṣẹ́ sí mi pé: “Wá, jẹ́ ká dá ìgbà tí a jọ máa pàdé ní àwọn abúlé tó wà ní Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ónò.”+ Àmọ́ ṣe ni wọ́n ń gbèrò láti ṣe mí ní ibi.
4 Nígbà tí Sáńbálátì+ gbọ́ pé a ti ń tún ògiri náà mọ, ó bínú, ó fara ya,* ó sì ń fi àwọn Júù ṣe yẹ̀yẹ́.
2 ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni Sáńbálátì àti Géṣémù ránṣẹ́ sí mi pé: “Wá, jẹ́ ká dá ìgbà tí a jọ máa pàdé ní àwọn abúlé tó wà ní Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ónò.”+ Àmọ́ ṣe ni wọ́n ń gbèrò láti ṣe mí ní ibi.