Nehemáyà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí náà, mo ro gbogbo rẹ̀ lọ́kàn mi, mo sì bá àwọn èèyàn pàtàkì àti àwọn alábòójútó wí, mo sọ fún wọn pé: “Kálukú yín ń gba èlé* lọ́wọ́ arákùnrin rẹ̀.”+ Yàtọ̀ síyẹn, mo ṣètò àpéjọ ńlá kan nítorí wọn.
7 Nítorí náà, mo ro gbogbo rẹ̀ lọ́kàn mi, mo sì bá àwọn èèyàn pàtàkì àti àwọn alábòójútó wí, mo sọ fún wọn pé: “Kálukú yín ń gba èlé* lọ́wọ́ arákùnrin rẹ̀.”+ Yàtọ̀ síyẹn, mo ṣètò àpéjọ ńlá kan nítorí wọn.