-
Ẹ́sírà 2:68, 69Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
68 Nígbà tí wọ́n dé ilé Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, lára àwọn olórí agbo ilé ṣe ọrẹ àtinúwá+ fún ilé Ọlọ́run tòótọ́, kí wọ́n lè tún un kọ́* sí àyè rẹ̀.+ 69 Ohun tí wọ́n kó wá sí ibi ìṣúra iṣẹ́ ilé náà gẹ́gẹ́ bí agbára wọn ṣe tó ni, ẹgbẹ̀rún mọ́kànlélọ́gọ́ta (61,000) owó dírákímà* wúrà àti ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) mínà* fàdákà+ pẹ̀lú ọgọ́rùn-ún (100) aṣọ fún àwọn àlùfáà.
-