ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 33:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ó sọ nípa Léfì pé:+

      “Túmímù rẹ* àti Úrímù  + rẹ jẹ́ ti ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin sí ọ,+

      Ẹni tí o dán wò ní Másà.+

      O bẹ̀rẹ̀ sí í bá a fà á lẹ́gbẹ̀ẹ́ omi Mẹ́ríbà,+

  • Diutarónómì 33:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  10 Jẹ́ kí wọ́n fi àwọn ìdájọ́ rẹ kọ́ Jékọ́bù,+

      Kí wọ́n sì fi Òfin rẹ kọ́ Ísírẹ́lì.+

      Jẹ́ kí wọ́n sun tùràrí láti mú òórùn dídùn jáde sí ọ*+

      Àti odindi ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́