-
Léfítíkù 23:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù keje yìí ni Àjọyọ̀ Àtíbàbà fún Jèhófà, ọjọ́ méje ni kí ẹ fi ṣe é.+
-
-
Léfítíkù 23:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Inú àtíbàbà ni kí ẹ gbé fún ọjọ́ méje.+ Kí gbogbo àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Ísírẹ́lì gbé inú àtíbàbà,
-
-
Diutarónómì 16:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “Ọjọ́ méje ni kí o fi ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà,+ nígbà tí o bá kó ọkà rẹ jọ láti ibi ìpakà, tí o sì mú òróró àti wáìnì jáde láti ibi ìfúntí rẹ.
-