-
Jẹ́nẹ́sísì 22:10-12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ábúráhámù sì nawọ́ mú ọ̀bẹ* kó lè pa ọmọ+ rẹ̀. 11 Àmọ́ áńgẹ́lì Jèhófà pè é láti ọ̀run, ó sì sọ pé: “Ábúráhámù, Ábúráhámù!” Ó dáhùn pé: “Èmi nìyí!” 12 Ó sì sọ pé: “Má pa ọmọ náà, má sì ṣe ohunkóhun sí i, torí mo ti wá mọ̀ báyìí pé o bẹ̀rù Ọlọ́run, torí o ò kọ̀ láti fún mi+ ní ọmọ rẹ, ọ̀kan ṣoṣo tí o ní.”
-