Jóṣúà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ilẹ̀ yín máa jẹ́ láti aginjù títí dé Lẹ́bánónì àti odò ńlá, ìyẹn odò Yúfírétì, gbogbo ilẹ̀ àwọn ọmọ Hétì,+ títí lọ dé Òkun Ńlá* ní ìwọ̀ oòrùn.*+ Ẹ́sírà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní àkókò yẹn, Táténáì gómìnà agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò* àti Ṣetari-bósénáì pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn wá bá wọn, wọ́n sì bi wọ́n pé: “Ta ló fún yín láṣẹ láti kọ́ ilé yìí, kí ẹ sì parí iṣẹ́* rẹ̀?”
4 Ilẹ̀ yín máa jẹ́ láti aginjù títí dé Lẹ́bánónì àti odò ńlá, ìyẹn odò Yúfírétì, gbogbo ilẹ̀ àwọn ọmọ Hétì,+ títí lọ dé Òkun Ńlá* ní ìwọ̀ oòrùn.*+
3 Ní àkókò yẹn, Táténáì gómìnà agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò* àti Ṣetari-bósénáì pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn wá bá wọn, wọ́n sì bi wọ́n pé: “Ta ló fún yín láṣẹ láti kọ́ ilé yìí, kí ẹ sì parí iṣẹ́* rẹ̀?”