-
Diutarónómì 3:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 A wá gba gbogbo ìlú rẹ̀. Kò sí ìlú tí a kò gbà lọ́wọ́ wọn, ọgọ́ta (60) ìlú ní gbogbo agbègbè Ágóbù, ilẹ̀ ọba Ógù ní Báṣánì.+ 5 Gbogbo ìlú yìí ni wọ́n mọ odi gàgàrà yí ká, wọ́n ní ẹnubodè àtàwọn ọ̀pá ìdábùú, pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àrọko.
-