-
Nehemáyà 6:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà tí wọ́n sọ fún Sáńbálátì, Tòbáyà+ àti Géṣémù ọmọ ilẹ̀ Arébíà+ pẹ̀lú àwọn ọ̀tá wa yòókù pé mo ti tún ògiri náà kọ́+ àti pé kò sí àlàfo kankan tó ṣẹ́ kù lára rẹ̀ (bó tilẹ̀ jẹ́ pé títí di àkókò yẹn, mi ò tíì gbé ilẹ̀kùn sí àwọn ẹnubodè),+ 2 ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni Sáńbálátì àti Géṣémù ránṣẹ́ sí mi pé: “Wá, jẹ́ ká dá ìgbà tí a jọ máa pàdé ní àwọn abúlé tó wà ní Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ónò.”+ Àmọ́ ṣe ni wọ́n ń gbèrò láti ṣe mí ní ibi.
-