-
Nehemáyà 13:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Mo tún rí i pé wọn ò fún àwọn ọmọ Léfì+ ní ìpín wọn,+ tó fi di pé àwọn ọmọ Léfì àti àwọn akọrin tó ń ṣe iṣẹ́ náà lọ lẹ́nì kọ̀ọ̀kan sí pápá wọn.+ 11 Torí náà, mo bá àwọn alábòójútó wí,+ mo sì sọ pé: “Kí ló dé tí ẹ jẹ́ kí wọ́n pa ilé Ọlọ́run tòótọ́ tì?”+ Ni mo bá kó wọn jọ, mo sì yàn wọ́n pa dà sí ipò wọn.
-