Nehemáyà 13:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin Jóyádà+ ọmọ Élíáṣíbù + àlùfáà àgbà ti di àna Sáńbálátì+ tó jẹ́ ará Hórónì. Torí náà, mo lé e kúrò lọ́dọ̀ mi.
28 Ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin Jóyádà+ ọmọ Élíáṣíbù + àlùfáà àgbà ti di àna Sáńbálátì+ tó jẹ́ ará Hórónì. Torí náà, mo lé e kúrò lọ́dọ̀ mi.