- 
	                        
            
            Nehemáyà 6:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Ọlọ́run mi, rántí Tòbáyà+ àti Sáńbálátì àti ohun tí wọ́n ṣe yìí, tún rántí Noadáyà wòlíì obìnrin àti àwọn wòlíì yòókù tó ń dẹ́rù bà mí nígbà gbogbo. 
 
-