Nehemáyà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+ Jòhánù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Adágún omi kan wà ní Jerúsálẹ́mù níbi Ibodè Àgùntàn+ tí wọ́n ń pè ní Bẹtisátà lédè Hébérù, ó ní ọ̀dẹ̀dẹ̀* márùn-ún.
3 Élíáṣíbù+ àlùfáà àgbà àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn àlùfáà, dìde láti kọ́ Ẹnubodè Àgùntàn.+ Wọ́n yà á sí mímọ́,+ wọ́n sì gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ nàró; wọ́n yà á sí mímọ́ títí dé Ilé Gogoro Méà+ àti títí dé Ilé Gogoro Hánánélì.+
2 Adágún omi kan wà ní Jerúsálẹ́mù níbi Ibodè Àgùntàn+ tí wọ́n ń pè ní Bẹtisátà lédè Hébérù, ó ní ọ̀dẹ̀dẹ̀* márùn-ún.